Yan ọ̀kan (kì í ṣe méjì, kì í ṣe mẹ́ta); NÍNÚ ohun kan ṣoṣo tó o fẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ ẹ́ sí, kó o sì máa ṣe é.
O ṣe deede lati ni ọpọlọpọ awọn ọgbọn, ṣugbọn o yẹ ki o ni ọkan ti o ṣe pataki, ati pe eyi ni ohun ti o ṣe afihan lori media media rẹ.
O n ba profaili awujọ rẹ jẹ nigba ti o ba kọ nipa ilera loni, lọla o kọ nipa imọ-ẹrọ, ohun ti o tẹle ti o n sọrọ nipa iṣelu, akoko miiran ti o n kọ ẹkọ nipa ọṣọ.
Kí lo fẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ ọ́ sí? O lè ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ òye, àmọ́ Ọ̀KAN péré lo gbọ́dọ̀ mọ̀!
O lè máa ṣe iṣẹ́ tó ju ẹyọ kan lọ, àmọ́ ó yẹ kó o ní IṢẸ́ kan tó jẹ́ olórí iṣẹ́ rẹ, gbogbo àwọn yòókù á sì wá di nǹkan kejì.
Ibi tó bá ṣe pàtàkì jù lọ fún ọ ni wàá ti máa lo agbára rẹ, ibẹ̀ lo máa darí àfiyèsí rẹ sí, ibẹ̀ lo máa lo èyí tó pọ̀ jù lọ nínú àkókò rẹ.
"Ohun kan ṣoṣo tí mo máa ń ṣe... "
Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù
Kí ni ohun kan tí àwọn èèyàn mọ̀ ọ́n sí?
Àánú àti Alaafia kí ó wà pẹ̀lú yín lónìí ⁇ ️
Comments